A A A A A
Facebook Instagram Twitter
Yoruba Bible (BMY) 2014

Saamu 291
Ẹ fi fún OLÚWA, ẹ̀yin ìran ọ̀run, Ẹ fi fún OLÚWA, ògo àti agbára.
2
Fi fún OLÚWA, àní ògo orúkọ Rẹ̀; sin OLÚWA nínú ẹwà ìwà mímọ́.
3
Ohùn OLÚWA ré àwọn omi kọjá; Ọlọ́run ògo sán àrá, OLÚWA náà, alágbára ń bẹ lóríi omi púpọ̀.
4
Ohùn OLÚWA ní agbára; ohùn OLÚWA kún fún ọláńlá.
5
Ohùn OLÚWA fọ́ igi kédárì; OLÚWA náà ló fọ́ igi kédárì Lébánónì.
6
Ó mú Lébánónì fo bí i ọmọ màlúù, àti Síríónì bí ọmọ àgbáǹréré.
7
Ohùn OLÚWA ń ya bí ọwọ́ iná mọ̀nà
8
Ohùn OLÚWA ń mi ihà. OLÚWA mi ihà Kádéṣì.
9
Ohùn OLÚWA ní ó lọ igi óákù, ó n mú abo àgbọ̀rín bí ó sì bọ́ igi igbó sí ìhòòhò. àti nínú tẹ́ḿpìlì Rẹ̀ gbogbo ohùn wí pé “Ògo!”
10
OLÚWA jókòó, Ó sì jọba lórí ìṣàn omi; OLÚWA jókòó lórí ìtẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọba títí láéláé.
11
Kí OLÚWA fi agbára fún àwọn ènìyàn Rẹ̀; bùkún àwọn ènìyàn Rẹ̀ pẹ̀lú àlàáfíà.Saamu 29:1

Saamu 29:2

Saamu 29:3

Saamu 29:4

Saamu 29:5

Saamu 29:6

Saamu 29:7

Saamu 29:8

Saamu 29:9

Saamu 29:10

Saamu 29:11Saamu 1 / Saa 1

Saamu 2 / Saa 2

Saamu 3 / Saa 3

Saamu 4 / Saa 4

Saamu 5 / Saa 5

Saamu 6 / Saa 6

Saamu 7 / Saa 7

Saamu 8 / Saa 8

Saamu 9 / Saa 9

Saamu 10 / Saa 10

Saamu 11 / Saa 11

Saamu 12 / Saa 12

Saamu 13 / Saa 13

Saamu 14 / Saa 14

Saamu 15 / Saa 15

Saamu 16 / Saa 16

Saamu 17 / Saa 17

Saamu 18 / Saa 18

Saamu 19 / Saa 19

Saamu 20 / Saa 20

Saamu 21 / Saa 21

Saamu 22 / Saa 22

Saamu 23 / Saa 23

Saamu 24 / Saa 24

Saamu 25 / Saa 25

Saamu 26 / Saa 26

Saamu 27 / Saa 27

Saamu 28 / Saa 28

Saamu 29 / Saa 29

Saamu 30 / Saa 30

Saamu 31 / Saa 31

Saamu 32 / Saa 32

Saamu 33 / Saa 33

Saamu 34 / Saa 34

Saamu 35 / Saa 35

Saamu 36 / Saa 36

Saamu 37 / Saa 37

Saamu 38 / Saa 38

Saamu 39 / Saa 39

Saamu 40 / Saa 40

Saamu 41 / Saa 41

Saamu 42 / Saa 42

Saamu 43 / Saa 43

Saamu 44 / Saa 44

Saamu 45 / Saa 45

Saamu 46 / Saa 46

Saamu 47 / Saa 47

Saamu 48 / Saa 48

Saamu 49 / Saa 49

Saamu 50 / Saa 50

Saamu 51 / Saa 51

Saamu 52 / Saa 52

Saamu 53 / Saa 53

Saamu 54 / Saa 54

Saamu 55 / Saa 55

Saamu 56 / Saa 56

Saamu 57 / Saa 57

Saamu 58 / Saa 58

Saamu 59 / Saa 59

Saamu 60 / Saa 60

Saamu 61 / Saa 61

Saamu 62 / Saa 62

Saamu 63 / Saa 63

Saamu 64 / Saa 64

Saamu 65 / Saa 65

Saamu 66 / Saa 66

Saamu 67 / Saa 67

Saamu 68 / Saa 68

Saamu 69 / Saa 69

Saamu 70 / Saa 70

Saamu 71 / Saa 71

Saamu 72 / Saa 72

Saamu 73 / Saa 73

Saamu 74 / Saa 74

Saamu 75 / Saa 75

Saamu 76 / Saa 76

Saamu 77 / Saa 77

Saamu 78 / Saa 78

Saamu 79 / Saa 79

Saamu 80 / Saa 80

Saamu 81 / Saa 81

Saamu 82 / Saa 82

Saamu 83 / Saa 83

Saamu 84 / Saa 84

Saamu 85 / Saa 85

Saamu 86 / Saa 86

Saamu 87 / Saa 87

Saamu 88 / Saa 88

Saamu 89 / Saa 89

Saamu 90 / Saa 90

Saamu 91 / Saa 91

Saamu 92 / Saa 92

Saamu 93 / Saa 93

Saamu 94 / Saa 94

Saamu 95 / Saa 95

Saamu 96 / Saa 96

Saamu 97 / Saa 97

Saamu 98 / Saa 98

Saamu 99 / Saa 99

Saamu 100 / Saa 100

Saamu 101 / Saa 101

Saamu 102 / Saa 102

Saamu 103 / Saa 103

Saamu 104 / Saa 104

Saamu 105 / Saa 105

Saamu 106 / Saa 106

Saamu 107 / Saa 107

Saamu 108 / Saa 108

Saamu 109 / Saa 109

Saamu 110 / Saa 110

Saamu 111 / Saa 111

Saamu 112 / Saa 112

Saamu 113 / Saa 113

Saamu 114 / Saa 114

Saamu 115 / Saa 115

Saamu 116 / Saa 116

Saamu 117 / Saa 117

Saamu 118 / Saa 118

Saamu 119 / Saa 119

Saamu 120 / Saa 120

Saamu 121 / Saa 121

Saamu 122 / Saa 122

Saamu 123 / Saa 123

Saamu 124 / Saa 124

Saamu 125 / Saa 125

Saamu 126 / Saa 126

Saamu 127 / Saa 127

Saamu 128 / Saa 128

Saamu 129 / Saa 129

Saamu 130 / Saa 130

Saamu 131 / Saa 131

Saamu 132 / Saa 132

Saamu 133 / Saa 133

Saamu 134 / Saa 134

Saamu 135 / Saa 135

Saamu 136 / Saa 136

Saamu 137 / Saa 137

Saamu 138 / Saa 138

Saamu 139 / Saa 139

Saamu 140 / Saa 140

Saamu 141 / Saa 141

Saamu 142 / Saa 142

Saamu 143 / Saa 143

Saamu 144 / Saa 144

Saamu 145 / Saa 145

Saamu 146 / Saa 146

Saamu 147 / Saa 147

Saamu 148 / Saa 148

Saamu 149 / Saa 149

Saamu 150 / Saa 150