Instagram
English
A A A A A

Matiu 1

1
Ìran Jésù Kírísítì, ẹni tí í ṣe ọmọ Dáfídì, ọmọ Ábúráhámù:
2
Ábúráhámù ni baba Ísáákì; Ísáákì ni baba Jákọ́bù; Jákọ́bù ni baba Júdà àti àwọn arákùnrin rẹ̀,
3
Júdà ni baba Pérésì àti Ṣérà, Támárì sì ni ìyá rẹ̀, Pérésì ni baba Ésírónù: Ésírónù ni baba Rámù;
Yoruba Bible (BMY) 2014

1
Èyí ni àkọsílẹ̀ ìran Jesu Kristi, ọmọ Dafidi, ọmọ Abrahamu.
2
Abrahamu bí Isaaki, Isaaki bí Jakọbu, Jakọbu bí Juda ati àwọn arakunrin rẹ̀.
3
Juda bí Peresi ati Sera, ìyá wọn ni Tamari. Peresi bí Hesironi, Hesironi bí Ramu.
Yoruba Bible (BM) 2010

1
IWE iran Jesu Kristi, ọmọ Dafidi ọmọ Abrahamu.
2
Abrahamu bí Isaaki; Isaaki si bí Jakọbu; Jakọbu si bí Juda ati awọn arakunrin rẹ̀;
3
Juda si bí Faresi ati Sara ti Tamari; Faresi si bí Esromu; Esromu si bí Aramu;
Yoruba Bible